Ìjàyè
Ìjàyè jẹ́ ìlú kan tí ó lágbára pupọ̀ láàrín àwọn ìlú àti ilẹ̀ Ọba ní ilẹ̀ Yorùbá. Ìlú Ìjàyè wà ní ara àwọn ìlú tí àwọn ọmọ Yorùbá tí wọ́n ságun ní Ọ̀yọ́-Ilé sá sí nígbà tí ogun àwọn Fúlàní kó ìlú Ọ̀yọ́-Ilé ní ọdún 1836.Ẹni tí ó jẹ́ adarí àti alákòóso ìlú náà ni Ààre Kúrunmí Ìjàyè[1]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Kurunmi of Ijaye, 1831-1862 : a biography of a militant Yoruba ruler in SearchWorks catalog". SearchWorks catalog. 2019-11-16. Retrieved 2019-12-16.