Ìjálá
Ìjálá sísun nípa Àkókó
àtúnṣeÌjálá fún àkókò kan nípa ìgbésí ayé àwùjọ kan ni èyí Ma ń sábà bá mu. Asùnjàlá tún lè yi padà bí Ó bá fẹ́ lòó fún àwùjọ mìíràn. Ìjálá tí Asùnjàlá bá sun Ma ń ṣàfihàn bí àwùjọ náà ṣe rí nípa ìrísí, ìhùwàsí àwọn ènìyàn ibẹ̀, àṣà, ìbáṣepọ̀ ètò ìṣèlú àti ètò ọrọ̀ ajé àwùjọ náà.[1]
Ewì nípa ẹyẹ àti ẹranko
àtúnṣeEranko, ẹyẹ, igi àti àwọn ńkan mìíràn wọ̀nyí ni asùnjálá ma ń mẹ́nu bà nínú ìjálá nígbà tí ó bá wà láàrín àwọn Ọdẹ ẹgbẹ́ rẹ̀ [2]
Ihà tí àwùjọ kọ sí ewì alohùn
àtúnṣeNínú lítíréṣọ̀ Yorùbá, oríṣiríṣi ewì alohùn ni ó wà tí ó yàtọ̀ sí Ìjálá. Bí Yorùbá ṣe ní ìjálá, ni wọ́n ní ègè, ọfọ̀, àásán, ìyẹ̀rẹ̀, rárà, ẹ̀sà àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ [3]
Oríkì nínú Ìjálá
àtúnṣeAwon ohun ti o maa n je akejaala logun ni o wa ni ori yii. Won maa n fi ijala ki eniyan a kii sii sabaa mo eni ti o seda iru ijala bee. Bi apeere, ijala ti o je mo oba Abiodun ni o wa ni ori yii. Lile ke ijala naa daadaa ni oriyin fun eni ti o ke ijala kii se ti pe boya ohun ni o seda re.
In the repertoire of a master ijala-artist, there is usually a preponderance of ijala poems which are eulogies on individual progenitors or groups of progenitors. The praise poems are anonymous classics which date back to the halcyon days of the Yoruba kingdom during the reign of King Abiọdun (1770-1830). In rendering these classics, the ijala-chanter takes credit for his ability to recall the texts accurately from memory and for his ability to chant them in the special traditional style. The credit for the composition of the texts belongs to anonymous authors of bygone eras....
Character Portraits in Ijala Poems
àtúnṣeEni kan ti akewi mo daadaa ni o ke ijala nipa re ni ori yii. Loooto, akewi yii yin in daadaa, sibe o so awon okodoro kan ti o koro nipa re.
The theme of many an ijala poem is the charater of a particular personage who is well known to the poet. The poet presents a character-portrait of the personage as a verbal salute to the personage himself and so the portrait tends to be biased in favour of him, but nevertheless, some unpalatable truths about him may be mentioned in the poem....
DR. Adeboye Babalọlá (1963), Ijala (A Form of Oral Poetry in Nigeria) Programme : October Lectures 1963, oju-iwe 1-37.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Àwọn Itọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Finnegan, Ruth (2014-09-23). [http://books.openedition.org/obp/1195 "8. Special Purpose Poetry—War, Hunting, and Work"] Check
|url=
value (help). Open Book Publishers. Retrieved 2019-12-15. zero width space character in|url=
at position 1 (help) - ↑ Ugochukwu, Françoise (2011-03-03). [/core/journals/africa/article/p-barrot-ed-nollywood-le-phenomene-video-au-nigeria-paris-lharmattan-pb-18-2-7475-7971-9-2005-175-pp/1FD1F96968BD9B140E3B6A96EE70C0F4 "P. Barrot (ed.), Nollywood – le phénomène video au Nigeria. Paris: L'Harmattan (pb €18 – 2 7475 7971 9). 2005, 175 pp. - Africa"] (in fr). Africa 77 (2): 287–288. doi:10.3366/afr.2007.77.2.287. ISSN 1750-0184. /core/journals/africa/article/p-barrot-ed-nollywood-le-phenomene-video-au-nigeria-paris-lharmattan-pb-18-2-7475-7971-9-2005-175-pp/1FD1F96968BD9B140E3B6A96EE70C0F4. Retrieved 2019-12-15.
- ↑ Ogúndèji., Philip Adédọ̀tun (1999-02-22). "Introduction to Yoruba oral literature = Ìfáàrà sí lítíréṣọ̀ alohùn Yorùbá (Book, 1991) [WorldCat.org]". WorldCat.org. Retrieved 2019-12-15.