Shahada tabi ìjẹ́ẹ̀rí (Arabic: الشهادة aš-šahāda as-shahadah.ogg audio ) (lati oro-ise [] error: {{lang}}: no text (help) šahida, "o jeri"), túmọ̀ sí "láti mo àti gbagbo láìsí ìfura, bíi jíjẹ́ẹ̀rí"; ó jẹ́ ọ̀kan nínú awon opo marun islam. Shahada ni ọ̀kan ìgbàgbọ́ nínú okan Allahu ta'âlâ àti gba Muhammad gẹ́gẹ́ bí ojise Olorun. Èyí yi ni pé:

lâ ilâha illallâh, Muḥammadur rasûlullâh (ni Larubawa)
Kò sí Ọlọ́run mìíràn àfi Ọlọ́run, Muhammad sì ni Òjíṣẹ́ Ọlọ́run (ni Yoruba)