Ìjọba
Ìjọba ni ikorajo ninu awujo kan, ile oloselu tabi agbajo to ni ase lati se ati fipase ofin, ilana, itele-ofin.
"Ijoba" ntoka si ijoba abele, isejoba oludalara to le ibile, onibinibi, tabi kariaye.
Ìjọba je "akojoegbe, to n joba lori agbegbe iselu kan",[1] "awon alase ninu awujo",[2] ati elo fun awon alase lati pase lori awujo.[3]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |