Àjọṣepọ̀

(Àtúnjúwe láti Ìjọbapọ̀)

Ìjọbapọ̀ tabi Orílẹ̀-èdè ìjọba àpapọ̀ tabi orile-ede apapo ni iru ijoba ibiti awon opo orile-ede ti darapo sokan lati ni ijoba kan soso larin ara won.

Maapu awon orile-ede ijoba apapo onibise