Ìkún omi Chad ọdún 2022

Ìkún omi Chad ọdún 2022 bẹ̀rẹ̀ ní Republic of Chad ní oṣù keje ọdún 2022 , ó sì di oṣù keje ọdún 2022.[1][2] Àwọn ọmọ orílẹ̀ èdè Chad tí ó tó 442,000 ni ó ti pàdánù ilé àti ọ̀nà wọn látàrí ìkún omi yìí, pẹ̀lú pẹ̀lú olú ìlú náà, N'Djamena.[1]

Okùnfà

àtúnṣe

Òjò líle ni ó rọ̀ ní Chad àti àwọn orílẹ̀-èdè agbègbè rẹ̀ ní Àárín àti Ìwọ oòrùn Áfríkà láàrin oṣù keje sí ìkẹ́jọ 2022, èyí sì fa ìkún ọmi ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ orílẹ̀ èdè.[1] Gégé bí Idriss Abdallah Hassan ṣe so "Orílẹ̀ èdè náà o ni àkọsílẹ̀ òjò tí ó tó bẹ̀ láti ọdún 1990."[1]

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. 1.0 1.1 1.2 1.3 Ramadane, Mahamat (2022-09-06). "Thousands battle 'catastrophic' floods after Chad's heaviest rains in 30 years". Reuters News. https://www.reuters.com/world/africa/thousands-battle-catastrophic-floods-after-chads-heaviest-rains-30-years-2022-09-06/. 
  2. "Unprecedented flooding in Chad hits more than 340,000 people". Radio France International. 2022-08-28. https://www.rfi.fr/en/africa/20220828-unprecedented-flooding-in-chad-hits-more-than-340-000-people.