Ìkún omi ní Ìpínlẹ̀ Benue ní ọdún 2017
Ìkún omi ní Ìpínlẹ̀ Benue ti ọdún 2017 jẹ́ ìkún omi tí ó ṣẹlẹ̀ ní oṣù kẹsàn-án ọdún 2017 ní Ìpínlẹ̀ Bẹ́núé, Nàìjíríà.[1] Ó mú kí àwọn ènìyàn tí ó tó ọgọ́rùn-ún ẹgbẹ̀rún sọ ilé àti ọ̀nà wọn nù,[2][3] ó sì ba ilé tí ó tó ẹgbẹ̀rún méjì jẹ́.[4]
Okùnfà
àtúnṣeÒjò tí ó rò fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọ̀sẹ̀ fa ìkún omi ní Ìpínlẹ̀ Benue, ọ̀pọ̀lọpọ̀ odò ni ó ya. Ìjọba ìbílẹ̀ ọ̀kànlélógún nínú mẹ́talélógún ni ìkún omi yìí ya wọ̀.[5] Ìṣẹ̀lẹ̀ ìkún omi wọ́pọ̀ ní àdúgbò náà nítorí ọ̀jọ̀ léra tí ó ma ń rọ̀ níbẹ̀ àti nítorí Odò Benue tí ó sàn gba ibẹ̀.
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "More than 100,000 displaced by flooding in central Nigeria" (in en). USA TODAY. Archived from the original on 2020-11-12. https://web.archive.org/web/20201112013848/https://eu.usatoday.com/story/news/world/2017/09/01/flooding-central-nigeria/624150001/.
- ↑ "Nigeria – Thousands Displaced by Floods in Benue State – FloodList". floodlist.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Copernicus. 5 September 2017. Retrieved 2017-09-10.
- ↑ Al Jazeera (1 September 2017). "Nigeria floods displace more than 100,000 people". www.aljazeera.com. Retrieved 2017-09-10.
- ↑ "Flood Hits Makurdi, Ravages Over 2,000 Homes • Channels Television". Channels Television. 2017-08-27. Retrieved 2017-09-10.
- ↑ "West and Central Africa: 2017 flood impact". Reliefweb 18 Oct 2017.