Ìlà ìpè (Sìm Card)
(Àtúnjúwe láti Ìlà ìpè)
Ìlà ìpè ni a lè pè ní Àmì ìdánimọ̀ fún oníbàárà (subscriber identity module) tí gbogbo ènìyàn ń pè ní SIM card, jẹ́ àmúpamọ́ [1]circuit) kan tí ó wà fún títọ́jú orúkọ àti àwọn àmì ìdánimọ̀ gbogbo tí oníbàárà bá fi sílẹ̀ lásìkò tí ó fẹ́ gba ìlà ìpè rẹ̀. Àwọn ohun tí oníbàárà fi sílẹ̀ yí ni yóò jẹ́ ohun tí wọ́n lè fi ṣe ìdámọ̀ rẹ̀ lórí ìtàkùn tàbí lórí ẹ̀rọ ìpè ìléwọ́. Ó ṣe é ṣe kí a fi orúkọ àti ìlà ìpè àwọn ènìyàn bí ẹbí, ọ̀rẹ́ àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ pamọ́ sórí ilà ìpè wa.
Ibi tí a ti lè lo ìlà ìpè
àtúnṣeA lè lo ìlà ìpè ní orí ẹ̀rọ ìléwọ́, sátáláìtì,, agogo ọrùn ọwọ́, ẹ̀rọ kọ̀mpútà tàbí àwọn ẹ̀rọ ayàwòrán tí óníkàápá irú rẹ̀. [2]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Buying a SIM Card in Nigeria". Too Many Adapters. 2019-03-14. Retrieved 2020-02-26.
- ↑ "SIM Card - GSM & Micro Compatible". T-Mobile. Retrieved 2020-02-26.