Omele jẹ́ ẹ̀yà ìlù kan tí ó wópọ̀ ní ilẹ̀ Adúláwọ̀. Àwọn ẹ̀yà Awúsá gúsù ilẹ̀ Nàìjíríà ni ó ni ìlù náà. Omele jẹ́ ìlù olójú mẹ́ta tí wọ́n máa ń fi igi lù.[1]