Ìlú Muṣin
Ìlú Muṣin agbègbè àti ìjọba ìbílẹ̀ kan ní Ìpínlẹ̀ Èkó.[1] [2] Ìlú yí wà ní àdojúkọ òpópó tó lọ sí ìlú Ìkẹjà. Muṣin jẹ́ ìlú kan tí ilé àt èrò pọ̀ sí gidi tí ètò ìmọ́ tótó sì mẹ́hẹ ní àárín Èkó, gẹ́gẹ́ bí ètò ìkànìyàn ọdún 2006 ṣe fìdí rẹ̀ múlẹ̀ wípé àwọn ènìyàn tí wọ́n ń gbe níbẹ̀ tó 633,009 níye.[3]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Lagos Police arrest 256 suspects for Mushin". BBC News Pidgin. 2018-03-02. Retrieved 2020-02-19.
- ↑ "Mushin". NigeriaCongress.org. Archived from the original on 2021-01-11. Retrieved 2007-04-08.
- ↑ "Mushin - Nigeria". Encyclopedia Britannica. Retrieved 2020-02-19.