Ìlọ́poméjì mítà

Ìlọ́poméjì mítà (ilopomeji metre) ni eyo dida SI fun ifesi ti ami-idamo rre je m2 (33A1 ninu Unicode). O je titumo gege bi ifesi anigunmerin ti awon egbeegbe re ni iwon mita kan pere.

Ìlọ́poméjì Mítà.