Ìmọ̀ ẹ̀dá-èdè
Ìmọ̀ ẹ̀dá-èdè (linguistics) ni ìmọ̀ nípa àbùdá èdè tí ọmọ ẹ̀dá ènìyàn n sọ tàbí sàmì (sign). Àwọn onímọ̀ ẹ̀dá-èdè máa ń ṣe àgbéyẹ̀wò bi èdè ṣe nííṣe pẹ̀lú ìròrí àti láàkàyè àti bí àwọn eniyan ṣe ń sàmúlò èdè láàrin àwùjọ.