Ìrànwọ́:Báwo lẹṣe le ṣe àtúnṣe ojúewé

Ìwé Ìmọ́-Ọ̀fẹ jẹ́ iwé, tí ó túmọ̀ sí ìwé tí ẹnikẹ́ni lè ṣàtúnṣe sí èyíkéyí ojú-ewé tí wọn kò dáàbòbò, tí yóò sì fi àtúnṣe rẹ̀ pamọ́ láti lè fi àtúnṣe rẹ̀ hàn sí gbogbo ènìyàn. Kódà, o kò ní láti dá àkọpamọ́ oníṣẹ́ kí o tó ṣàtúnṣe tó jọjú sí èyíkéyí àyọkà tí ó bá nílò àtúnṣe. Àmọ́ ṣá, bí o bá forúkọ sílẹ̀ tàbí dá àkọpamọ́ orúkọ oníṣẹ́ (Username) rẹ, yóò fún ọ láànfàní láti lè mọ iye àkòrí àyọkà tí o bá dá sílẹ̀ tàbí ṣàtúnṣe sí. Wikipedia editor!

Àkíyèsí: O lè lo sandbox láti fi ṣe ìdánrawò lórí bí o ṣe lè ṣàtúnṣe ojú-ìwé.

Ṣíṣàtúnṣe àyọkàÀtúnṣe

Ṣíṣàtúnṣe púpọ̀ ojú-ewé kò nira rárá, kàn tẹ "Àtúnṣe" tàbí "Àtúnṣe àmì-ọ̀rọ̀" ní orí ìlà ṣíṣàtúnṣe ní òkè ojú-ewé Wikipẹ́día lábẹ́ àwòrán agogo àti orúkọ oníṣẹ́.section-edit link). Bí ó bá ti tẹ̀ẹ́, yóò gbé ọ wá sí ojú ewé tí wà á ti lánfàní láti ṣàtúnṣe tó bá wù ọ́ sí àyọkà tí o fẹ́ túnṣe gan an.

Fáìlì:Àpẹẹrẹ bí a ṣe ń ṣàtúnṣe ojú-ewé box.png
Edit box showing the wikimarkup for this page. You can see the markup for a level-two heading, and bold-face.


Bí o bá ní ohunkóhun tí o fẹ́ fi kún ojú-ewé, jọ̀wọ́ fi ìtọ́ka si, gẹ́gẹ́ bí àwọn àyọka tí kò ní ìtọ́ka sí yóò di píparẹ́. Bí o bá ti parí pẹ̀lú àtúnṣe, kọ edit summary sínú àkámọ́ kékeré. O sì lè lo ìlànà ìkékúrú bíi legend. Bí o bá sì fẹ́ wo bí àtúnṣe rẹ ṣe rí, tẹ bọ́tìnì "Àyẹ̀wò". Tí ohun tí o bá ṣe bá ti tẹ́ ọ lọ́rùn tẹ "Ṣàtẹ́jáde" aláwọ̀ búlúù tí ó wà lápá òsì lẹ́gbẹ̀ẹ́ (Ṣàtẹ̀jáde). Àtúnṣe rẹ̀ yóò hàn lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀ tí o bá ti ṣe èyí fún gbogbo ayé rí. Wo èyí fún àpẹẹrẹ

 
Edit commands


You can also click on the "Discussion" tab to see the corresponding talk page, which contains comments about the page from other Wikipedia users. Click on the "new section" tab to start a new section, or edit the page in the same way as an article page