Ìròyìn Oṣù Kàrún 2012
- Ìṣọ̀kan Akáríayé fún Ìṣiṣẹ́ògùn Ògidì àti Oníàmúlò fọwọ́sí àwọn orúkọ flerovium àti livermorium fún àwọn apilẹ̀ṣẹ̀ méjì tí orúko ìgbàdíẹ̀ wọn jẹ́ ununquadium àti ununhexium.
- Ààrẹ Làìbéríà tẹ́lẹ̀ Charles Taylor jẹ́ jíjù sí ẹ̀wọ̀n fún 50 ọdún fún ipa tó kó nínú àwọn ìwà búburú tò ṣẹlẹ̀ nígbà Ogun Abẹ́lé Siẹrra Lẹ́ónè.
- Kápsúlù Dragon tó jẹ́ gbígbera látọwọ ilé-iṣẹ́ SpaceX di ìfòlókè alájé àkọ́kọ́ tó dé Ibùdó Òfurufú Akáríayé.
- Vladimir Putin di Ààrẹ Rọ́síà fún ìgbà kẹta.
- François Hollande jẹ́ díbíbòyàn sí ipò Ààrẹ ilẹ̀ Fránsì.