Ìtẹ̀léntẹ̀lé Cauchy

Ninu imo isiro, itelentele Cauchy, ti a s'oloruko fun Augustin Cauchy, je itelentele ti awon afida (element) re n sunmo ara won bi itelentele ohun ba se n po si. Ni soki, ti a ba jusile nomba pato afida lati ibere itelentele ohun, a le so ijinnasi togaju larin afida meji di kekere bo ba se wu wa.

Itelentele Cauchy fun awon nomba gidiÀtúnṣe

Itelentele kan,

 

fun nomba gidi je ti Cauchy, ti fun gbogbo nomba gidi alapaotun ti r > 0, nomba odidi N alapaotun yio wa fun won to je pe fun gbogbo awon nomba odidi m, n>N a ni