Ìwé Àṣẹ Aṣàlàyé Ọ̀fẹ́ GNU
GNU Free Documentation License (GFDL) (Ìwé Àṣẹ Aṣàlàyé Ọ̀fẹ́ GNU) jẹ́ ìwé àṣẹ copyleft fún aṣàlàyé ọ̀fẹ́ látọwọ́ Free Software Foundation (FSF) fún àwọn iṣẹ́ ọwọ́ GNU. Àtẹ̀jáde 1.3 ni ó wà lọ́wọ́, ìkọ oníbiṣẹ́ rẹ̀ ṣe é rí ní àdírẹ́sì http://www.gnu.org/copyleft/fdl.html.
Àmí ilé-iṣẹ́ GNU, gnu | |
Olùdákọ | Free Software Foundation |
---|---|
Àtẹ̀jáde | 1.3 |
Atẹ̀wéjáde | Free Software Foundation, Inc. |
Títẹ̀jáde | Àtẹ̀jáde lọ́wọ́: 3 Oṣù Kọkànlá, odún 2008 |
Bíbámu mọ́ DFSG | Bẹ́ẹ̀ni, láìsí abala kankan tó yàtọ̀ |
Atòlànà kọ̀mpútà ọ̀fẹ́ | Bẹ́ẹ̀ni |
Bíbámu mọ́ GPL | Bẹ́ẹ̀kọ́ |
Copyleft | Bẹ́ẹ̀ni |
Ìwé àṣẹ náà wà fún aṣàlàyé atòlànà kọ̀mpútà àti bákanáà fún àwọn ìjésì míràn àti fún àwọn ìwé ìlànà. Èyí mudájú pé àwòkọ kọ̀ọ̀kan èlò náà, bótilẹ̀jẹ́ láláàtúnṣe, yíò ní ìwé àṣẹ kannáà. Àwọn àwòkọ wọ̀nyí ṣe é tà, sùgbọ́n eni tó tà gbọdọ̀ mọ̀ pé elòmíràn náà lè ṣe àtúnṣe síi láì gbàṣẹ lọ́wọ́ rẹ̀. Wikipedia ni iṣẹ́ ọwọ́ tótóbijùlọ aṣàlàyé ọ̀fẹ́ tó únlo ìwé àṣẹ yìí.
Àwọn ìjápọ̀ òde
àtúnṣe- GNU Free Documentation License v 1.3 (ìkọ àtilêwá GFDL)
- GNU Free Documentation License v 1.2 (ìkọ àtilêwá GFDL)
- Ìyédèpadà Yorùbá fún GFDL v 1.2
- http://www.gnu.org/home.html
- http://www.diaplous.org/index.php?s=48 Archived 2008-05-01 at the Wayback Machine.
- https://pembeanne.xyz/ Archived 2021-03-02 at the Wayback Machine.
- https://odevhaber.xyz/ Archived 2021-02-25 at the Wayback Machine.
- https://www.addurl.link/ Archived 2020-10-26 at the Wayback Machine.
- https://www.coinsnet.xyz/ Archived 2021-05-02 at the Wayback Machine.
- https://www.yorgunadam.org/ Archived 2021-05-02 at the Wayback Machine.