Ìwé Ìrìnà ni àkójọ pọ̀ ìwé ìdánimọ̀ tí ìjọba orílẹ̀-èdè kan sì fi òntẹ̀ lù fún ìrìn-àjò ọmọ orílẹ̀-èdè bẹ́ẹ̀. Àmọ́ èyí kìí ṣi ìwé àṣẹ ìgbélùú rárá. Ìwé yí wà fún ìrìn-àjò lọ sí orílẹ̀-èdè mìíràn.[1] Àwọn ohun tí ó ṣe kókó jùlọ ni orúkọ ẹni tí ó ni ìwé ìrìnà náà, ibi tí wọ́n ti bíi, ọjọ́ ìbí, àwòrán ìdánimọ̀ pélébé, ìbuwọ́lù àti àwọn nkan tí a lè fi dá ẹni tí ó ni ìwé ìrìnà náà. Púpọ̀ nínú àwọn orílẹ̀-èdè ni wọ́n ti gùn lé ìpèsè ìwé ìrìnà onítẹ̀ka tí ó ní àmì ìdánimọ̀ chip nínú, tí yóò dènà ṣíṣe ayédèrú ìwé ìrìnà lọ sí ìlú mìíràn. [2]

Dutch ordinary, Nepalese diplomatic, Polish ordinary, and People's Republic of China service passports
Passport control at an airport.

.[3]

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe