Ìwé Ẹ́sítérì jẹ́ ẹsẹ Bíbélì Mímọ́ tó sọ̀rọ̀ nípa Ẹ́sítérì, múdíá, bí ó ṣe rí àánú Ọlọ́run gbà, tó di aya ọba, tí ó sì tún kó àwọn Ísírẹ́lì yọ lọ́wọ́ Hámánì ọ̀tá wọ́n, abbl.

Ẹ́sítérì aya ọba.