Ìwé Dáníẹ́lì jẹ́ ẹsẹ Bíbélì Mímọ́ tó sọ̀rọ̀ nípa Dáníẹ́lì àti àwọn ìdojúkọ rẹ̀ ní ilẹ̀ àjòjì Bábílónì lọ́pọ̀, bẹ́ẹ̀ pẹ̀lú àkọsílẹ̀ àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ oríṣiríṣi mìíràn, bí i àwọn ọmọ Hébérù mẹ́ta Ṣẹ́díráákì, Mẹ́ṣàákì, àti Àbẹ́dínígò. Abbl.

Dáníẹ́lì nínú túbú àwọn kìnnìún.