Ìwé Númérì

ojúewé ìṣojútùú Wikimedia

Ìwé Númérì jẹ́ ìwé Bíbélì Mímọ́ tó sọ̀rọ̀ nípa àwọn ọmọ Ísírẹ́lì àti àwọn ìlàkàkà àti ìrìnàjò wọn nínú aginjù, ìyẹn bí wọ́n ṣe kúrò ní ilẹ Sínáì, tí wọ́n lọ sí ilẹ̀ ìlérí. Ìwé yìí tún sọ̀rọ̀ nípa oríṣi ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn àríwísí wọn lórí ìjìyà wọn.

Ìwé Númérì.