Ìwé Sámúẹ́lì
Ìwé Sámúẹ́lì jẹ́ ìwé Bíbélì Mímọ́ tó sọ̀rọ̀ nípa Sámúẹ́lì, ìbí rẹ̀, bí ó ti ṣe dàgbà nínú ìjọ lábẹ́ wòlíì Ọlọ́run kan Élì, tí ó sì jẹ́ láti ìgbà èwe rẹ̀ ni Ọlọ́run ti pè é. Sámúẹ́lì ni wòlíì Ísírẹ́lì tó kàn lẹ́yìn Élì, tí ó sì ń fi iṣẹ́ tí Ọlọ́run ran gba àwọn ènìyàn rẹ̀ nípa yíyàn ọba Sọ́ọ́lù gẹ́gẹ́ bí i ọba Ísírẹ́lì àkọ́kọ́. Tí ó sì tún sọ̀rọ̀ nípa àyọrísí àwon àwọn Ísírẹ́lì gẹ́gẹ́ bí i olùborí lórí àwọn Filísínì, àti ìgbàgbọ́ nínú Ọlọ́run láti má kọ àwọn ènìyàn rẹ̀ sílẹ̀. Abbl.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |