Òfin kòtò àkọ́kọ́
Òfin kòtò àkọ́kọ́ tàbí Òfin kòtò jẹ́ òwe tí ó sọ wípé "tí o bá ba ara rẹ nínú kòtò, kí o maa ṣe gbẹ́ ẹ síwájú síi".[1][2] Ìtumọ̀ rẹ̀ ni wípé tí o ba bá ara rẹ ní ipò tí kò dára, ki o dúró kí o sì ṣe àtúnṣe oun tí ò ń ṣe tẹ́lẹ̀ kí o má sẹ tẹ̀síwájú.
Ibi tí ó ti jẹyọ
àtúnṣeOríṣiríṣi ibi ni wọ́n rò wípé òwe yìí ti jẹyọ. Ó yọjú nínú àtẹ̀jáde ojú ewé kẹfà ti The Washington Post ti ọjọ́ karùndínlọ́gbọ̀n Oṣù kẹwá ọdún 1911, báyìí: "Kò ṣeéṣe kí ọlọ́gbọ́n ènìyàn bá ara rẹ̀ nínú kòtò, kí ó lọ ibiṣẹ́ kí ó sì tún maa gbẹ́ẹ lọ..."[3] Nínú The Bankers Magazine wọ́n ṣe àtèjáde rẹ̀ ní ọdún 1964 báyìí:"Jẹ́ kí n sọ fún ẹ nípa òfin kòtò:Tí o bá bá ara rẹ nínú kòtò, maa ṣe gbẹ́ẹ síwájú si."[4] Wọ́n sọ wípé Will Rogers, aláwàdà ará Amẹ́ríkà ni ó sọ ọ̀rọ̀ tí ó wà níwájú àmì ìṣafihan.[5]
Ní UK wọ́n pèé ní "Òfin kòtò ti Healey àkọ́kọ́"[2] lórúkọ olóṣèlú Denis Healey, tí ó pòwe yìí ní ọdún 1980 àti lẹ́yìn ìgbà náà.[1]
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣeÀwọn ìjápọ̀ látìta
àtúnṣe- Àwọn ọ̀rọ̀ tí ó ní ṣe pẹ̀lú Denis Healey ní Wikiquote