Òrìṣà (tí wọ́n máa ń pè ní Orisa tàbí Orixa) jẹ́ ẹ̀mí àìrí tàbí irúmọlẹ̀ tí wọ́n ṣàfihàn ìṣesí ìgunwà Olodumare (God) nínú Yorùbá ìṣe ẹ̀mí tàbí ìṣe ẹ̀sìn.[1][2]

Iya oosa nlu ilu