Şalom
Şalom je iwe-iroyin olosoose awon Ju tounje titejade ni Turki. Oruko re wa lati ikoleta oro ni ede Turki fun oro Heberu Shalom. O je didasile ni 29 Osu Kewa 1947 latowo oniroyin omo Ju Turki Avram Leyon. O unje titesiwe ni Istanbul o si unjade ni ojoojo Ojoru. Ayafi ojuewe re kan to je pelu ede Ladino, ede Turki ni won fi un tejade. İvo Molinas ni olutejade re. Yakup Barokas ni olootu agba. Iye itakiri re je bi 5,000.
Fáìlì:Shalom logo.png | |
Type | Weekly newspaper |
---|---|
Format | Tabloid |
Owner | Gözlem Gazetecilik Basın ve Yayın A.Ş. |
Publisher | İvo Molinas |
Editor | Yakup Barokas |
Founded | 29 October 1947 |
Headquarters | Atiye Sokak, Polar Apt. No 12/6, 30204 Teşvikiye, İstanbul, Turkey |
Circulation | 5,000 Weekly |
Official website | Şalom official website |
E tun wo
àtúnṣeAwon ijapo nita
àtúnṣe
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |