Olúṣẹ́gun Agbájé tí wọ́n bí ní ọdún 1964 jẹ́ alákòóso àti olùdarí ilé ìfowó-pamọ́ Guaranty Trust Bank ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[1] Ó tún jẹ́ adarí fún ìgbìmọ̀ MasterCard Advisory Board ti àrin gbùngbùn ilà Oòrùn ilẹ̀ Adúláwọ̀.

Ṣẹ́gun Julius Agbájé
Ọjọ́ìbíOlúṣẹ́gun Agbájé
Ìpínlẹ̀ Èkó, orílẹ̀-èdè Nàìjíríà
Iléẹ̀kọ́ gíga
Iṣẹ́Banker, entrepreneur
Ìgbà iṣẹ́1991-Present
Gbajúmọ̀ fúnGTBank executive

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Mr. Segun Agbaje - Managing Director/CEO". Retrieved 14 January 2017.