Ṣade Baderinwa

(Àtúnjúwe láti Ṣadé Bádérìnwá)

Wọ́n bí Fọláṣadé Ọláyínká Bádérìnwá, tí wọ́n mọ̀ lẹ́nu iṣẹ́ rẹ̀ sí Ṣadé Bádérìnwá (/ˈʃɑːd ˈbɑːdərɪnwɑː/ /ˈʃɑːd ˈbɑːdərɪnwɑː/ SHAH-day BAH-dər-in-wah), ní ọjọ́ kẹrìnlá Oṣù kẹ́rin, 1969. (born April 14, 1969) jẹ́ olùdarí ètò ní orí  WABC ìkànì kéje (Channel 7). Bákan náà ni ó tún ṣe amúgbá-lẹ́gbẹ́ lórí ètò olósẹ̀-ọ̀sẹ̀ pẹ̀lú Diana Williams tí ó ma ń wáyé ní dédé agogo márun ìrọ̀lẹ́ (Eyewitness News) àti ìròyìn alágo mọ́kànlá (11.pm news) kan pẹ̀lú Bill Ritter.

Sade Baderinwa
Ọjọ́ìbíFolasade Olayinka Baderinwa
14 Oṣù Kẹrin 1969 (1969-04-14) (ọmọ ọdún 55)
Baltimore, Maryland
Iṣẹ́Journalist
Notable credit(s)Co-anchor of Eyewitness News at 5:00pm for WABC-TV (2003-present) with Diana Williams and the Co-anchor for "Eyewitness News at 11" (2011-present) with Bill Ritter.

Bàbá rẹ̀ jẹ́ Yor̀ubá ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí ìyá rẹ̀ sì jẹ́ ọmọ ilẹ̀ German. Orúkọ rẹ̀ àkọ́kọ́ ni "Fọláṣadé", tó túmọ̀ sí "Someone who uses wealth as crown".[1] Ó jáde ní ilé ẹ̀kọ́ àgbà ti University of Maryland College Park.[2] Lẹ́yìn tí ìyá rẹ̀ ti ja kalẹ̀ láti ọmọdé tí ẹnìkan tí ó jẹ́ African American sì gbàá tọ́ àmọ́ òun àti bàbá rẹ̀ tó ń bẹ ní Nàìjíríà ń sọ̀rọ̀ déédé.[3]

Ṣadé dara pọ̀ mọ́ ilé iṣẹ́ WABC ní ọdún 2003 lẹ́yìn tí ó ṣe díẹ̀ ní ìlú abínibí rẹ̀ Baltimore, Maryland, ní bi tí ó ti darí ètò ìròyìn lórí WBAL-TV fún bí ọdún mẹ́ta. Ṣadé rọ́pò Roz Abrams, tí ó kúrò nílé iṣẹ́ yìí ní ọdún 2003 láti gbaṣẹ́ ní agogo márùún sí mọ́kànĺa alẹ́ (5 and 11 p.m.) ní  WCBS-TV.[4]  Ní ọjọ́ kẹtàdín-lógún Oṣù kéje, ọdún 2004 (July 23, 2004) nígbà tí ó ń múra láti jábọ̀ ìṣẹ̀lẹ̀ omíyalé tí ó ṣẹlẹ̀ ní Hackensack, New Jersey , ní ọlọ́kọ̀ kán gba tí ó sì sálọ (hit and run).[5][6][7] Ṣadé padà sídìí iṣẹ́ rẹ̀ (Eyewitness News on December 13, 2004). lẹ́yìn ọ̀pọ̀ iṣẹ́ abẹ àti àyẹ̀wò ìgb̀a-dégb̀a,  physical therapy,[8]

Bádérìnwá ni ó jẹ́ akéde ètò ọ̀sán tẹ́lẹ̀ kí wọ́n tó gbe lọ sí ìdí ètò ago márùún ìrọ̀lẹ́ (5:p.m) pẹ̀lú Diana Williams. Ṣadé hàn nínú The View  gẹ́gẹ́ bí olùgbàlejò lórí October 27, 2006. Bákan náà, ní Oṣù karùún (May, 2011), Bádérìnwá di amúgbá-lẹ́gbẹ̀ẹ́ ìròyìn alágo mọ́kànlá (11 p.m. news) pẹ̀lú Bill Ritter, tí òun náà sì ń rọ́pò Liz Cho, tí ó kúrò ní ip̀o adarí fún ìwé ìròyìn (new WABC 4 p.m newscast), èyí tí ó fẹsẹ̀ múlẹ̀ lẹ́yìn tí The Oprah Winfrey Show kásẹ̀ kúrò nílẹ̀ tán tí Bádérìnwá sì tẹ̀ síwájú láti ma bá ètò ìròyìn alágo márùn ún 5 p.m. sí 11 p.m. lọ.[9]


Àwọn ìtọ́ka sí

àtúnṣe
  1. Meaning of Folasade in Nigerian.name
  2. Biography at "Sade Baderinwa". WABC-TV. Archived from the original on 2007-02-12. https://web.archive.org/web/20070212045745/http://abclocal.go.com/wabc/story?section=bios&id=3301260. Retrieved 2007-04-08. 
  3. Stephanie Shapiro (May 12, 2002). "Anchor In Her Life". The Baltimore Sun. Archived from the original on 2011-12-10. https://web.archive.org/web/20111210151731/http://articles.baltimoresun.com/2002-05-12/news/0205130313_1_sade-baderinwa-house-anchor. 
  4. St. George, Donna (2006-10-31). "A Politician Who Thinks Like a Linebacker". Washington Post. pp. A01. https://www.washingtonpost.com/wp-dyn/content/article/2006/10/30/AR2006103001361.html. Retrieved 2006-12-03. 
  5. WABC-TV: Sade Baderinwa Update: Cops Hunt Driver, $5,000 Reward Offered Archived 2004-12-31 at the Wayback Machine.
  6. Huff, Richard; Hufte, Tom (2004-07-24). "Daily News: TV news anchor struck in hit-and-run". New York Daily News. Archived from the original on 2006-06-29. https://web.archive.org/web/20060629110701/http://www.nydailynews.com/front/story/215341p-185399c.html. Retrieved 2006-12-03. 
  7. "WBAL-TV: Sade Baderinwa talks about accident that nearly killed her". TheWBALChannel.com. 2005-02-24. Archived from the original on 2006-11-27. https://web.archive.org/web/20061127095454/http://www.thewbalchannel.com/entertainment/4227367/detail.html. Retrieved 2006-12-03. 
  8. Huff, Richard (2004-12-17). "Ch. 7 anchor's road to recovery". New York Daily News. Archived from the original on 2005-12-27. https://web.archive.org/web/20051227045952/http://www.nydailynews.com/entertainment/story/262757p-224977c.html. Retrieved 2006-12-03. 
  9. Huff, Richard (2011-04-22). "Inner Tube: Liz Cho, David Novarro to anchor 'Eyewitness News First at 4,' taking 'Oprah' timeslot". New York Daily News. http://www.nydailynews.com/entertainment/tv/2011/04/22/2011-04-22_inner_tube_liz_cho_david_novarro_to_anchor_eyewitness_news_first_at_4_taking_opr.html. Retrieved 2011-04-24.