Ẹ̀wà Àgànyìn
Ẹ̀wà Àgànyìn[1] jẹ́ oúnjẹ àdúgbò tí ó wọ́pọ̀ ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìpínlẹ̀ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà pàá pàá jùlọ Ìpínlẹ̀ Èkó [2] Wọ́n ma ń sábà se ẹ̀wà yí kí ó rọ̀ tàbí kí ó fọ́ dára dára .[3] wọ́n sábà má ń jẹ́ ẹ̀wà yi pẹ̀lú ata díndín tí wọ́n fepo gbá ,[4] àmọ́, ata náà ń ta gidi. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn ni wọ́n máa ń ṣe ìkékúrú orúkọ ẹ̀wà náà 'Ẹ̀wà G'. Àwọn ńkan mìíràn tí wọ́n ma ń fi pèsè ata tàbí ọbẹ̀ rẹ̀ ni epo pupa,Àlùbọ́sà, Edé àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.
Alternative names | Ewa Aganyin |
---|---|
Type | Street food |
Course | Side Dish, Snack |
Place of origin | Nigeria |
Main ingredients | Black Eyed Beans, Bell Pepper, Black/Cameroon Pepper, Onion |
Àdàkọ:Wikibooks-inline
|
Bí wọ́n ṣe ń jẹẹ́
àtúnṣeỌ̀pọ̀ ènìyàn ló máa ń fi ẹ̀wà yí jẹ búgan tàbí búrẹ́dì, ti ó sì máa ń jẹ́ kí ó dùn yàtọ̀. Oúnjẹ yí jẹ́ èyí tí ó gbajúmọ̀ láàrín àwọn ènìyàn ilẹ̀ Adúláwọ̀
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Ewa Agoyin Recipe". Mamador. Retrieved February 5, 2018.
- ↑ Ewa Aganyin: Popularity of street food soaring in Lagos. September 19, 2015. Daily Trust
- ↑ "23 Nigerian Foods The Whole World Should Know And Love". Buzzfeed.com. June 24, 2015. Retrieved December 21, 2017.
- ↑ "Seven Popular Bukkas In Lagos. October 2, 2017. The Guardian.". Archived from the original on February 24, 2020. Retrieved November 29, 2019.