Ẹ̀yà Bishari
Àwọn Bishari (Lárúbáwá: البشارية, tàbí البشاريين, romanized: al-Bishāriyyīn; Beja: Oobshaari) jẹ́ ẹ̀yà kan tí ó gbé ní apá Àríwá ìlà oòrùn Áfríkà. Wọ́n wà lára àwọn ènìyàn Beja. Yàtò sí èdè Arabic tí wọ́n ń sọ, àwọn ènìyàn Bishari tún ń sọ Beja language, èdè tí ó jẹ́ ara àwọn ìdílé Afroasiatic.
MPP-Hm1.jpg |
Àpapọ̀ iye oníbùgbé |
---|
42,000 |
Regions with significant populations |
Sudan
, Egypt |
Èdè |
Beja (Bidhaawyeet), Arabic |
Ẹ̀sìn |
Ẹ̀yà abínibí bíbátan |
other Beja |
Ibi tí wọ́n gbé
àtúnṣeÀwọn ẹ̀yà Bishari gbé ní Asálẹ̀ Nubian ní Sudan àti apá Gúúsù Egypt. Wọ́n gbé ní Atabai (tàbí Atbai) láàrin Odò Nile àti Red Sea, àríwá Amarar àti gúúsù ibi tí àwọn ènìyàn Ababda wà, láàrin asálẹ̀ Nubian àti pẹ̀tẹ́lẹ̀ Nile, ibẹ̀ ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ òkúta àti àpáta.[1]
Iye àwọn tó jẹ́ ẹ̀yà náà tó ẹgbẹ̀rún méjìlélógójì (42,000).
Èdè
àtúnṣeÈdè abínibí awọn ẹ̀yà Bishari ni èdè Beja. Ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn èdè ní ìdílé Afroasiatic.[2] Àwọn Beja tí ó tún ń gbé ní orílẹ̀ èdè Sudan ń sọ èdè Sudanese Arabic.[2]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Starky, Janet. "Perceptions of the Ababda and Bisharin in the Atbai". University of Durham. Archived from the original on 10 March 2006. Retrieved 23 November 2016. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ 2.0 2.1 "Bedawiyet". Ethnologue. Retrieved 22 November 2017.