Eyo Festival

(Àtúnjúwe láti Ẹ̀yọ̀)

Eyo Festival jẹ́ òrìṣà ayẹyẹ tí a mọ̀ mọ́ Erékùsù Èkóìpínlẹ̀ Èkó lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Ó jẹ́ òrìṣà tí àwọn ẹgbẹ́ awo máa ń fi ń ṣẹ̀yẹ ìkẹyìn fún olóyè pàtàkì tàbí ọba tí ó bá wàjà ní Èkó.[1] Nígbà mìíràn ẹ̀wẹ̀, wọn a máa gbé Ẹ̀yọ̀ jáde fún àwọn ayẹyẹ pàtàkì mìíràn ní Erékùṣù Èkó.[2]. Ọdọọdún ni wọ́n máa ń ṣodún Ẹ̀yọ̀ ni Erékùṣù Èkó.

Eyo Iga Olowe Salaye masquerade tó ń fò sókè.

Àwòrán

àtúnṣe

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "EYO FESTIVAL". Ochulo. 2018-05-15. Retrieved 2020-01-24. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  2. "Eyo festival: History and features - Vanguard News". Vanguard News. 2017-06-02. Retrieved 2020-01-24.