Ẹgbẹ́ Rẹ̀públíkánì (USA)
Ẹgbẹ́-òṣèlú Rẹ̀púbílíkánnì (Republican Party) jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ẹgbẹ́ òṣèlú meji pàtàkì lónìí ní orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà.Àwọn alátakò okowò ẹrú ló dá ẹgbẹ́ òṣèlú yìí sílẹ̀ lọ́dún 1854. Wọ́n pè é ní GOP tó dúró fún Grand Old Party, bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ẹgbẹ́ òṣèlú yìí kéré sí ẹgbẹ́ rẹ̀ kejì lọ́jọ́ orí, àwọn ènìyàn gbà á gẹ́gẹ́ bí ẹgbẹ́ òṣèlú pàtàkì lórílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |