Ẹlẹ́sìn Krístì tabi Omo leyin Kristi tabi lasan bi Onigbagbo ni eni to nigbagbo ninu Esin Kristi eyi to je esin Abrahamu to gba pe Olorun kan soso lowa to dalori igbesiaye ati eko Jésù ara Nasareti ti won gba bi Messiah to je sisotele ninu Majemu Laelae, ati Omo Olorun.[1][2]ItokasiÀtúnṣe

  1. define.asp?key=13408&dict=CALD&topic=followers-of-religious-groups "Definition of Christian" Check |url= value (help). Cambridge Advanced Learner's Dictionary. Cambridge University Press. Retrieved 2010-18-01.  Check date values in: |access-date= (help)
  2. "BBC — Religion & Ethics — Christianity at a glance", BBC