Ọ̀rọ̀:Àbò
Olóòtú àgbà User:T Cells àti User:Demmy, mo ń fi àsìkò yí béèrè fún pípa ojú-ewé Àbò rẹ́ látàrí dídá akòrí àyọkà tí kò ní ọgbà ọ̀rọ̀ tí ó ṣe é tọ́ka sí láti ọwọ́ oníṣẹ́ tí kò ní orúkọ. Kí ẹ sì bá wa ṣe ìkìlọ tako irúfẹ́ ìṣeẹ́ bayi láti èwe onítọ̀hún àti àwọn tí wọ́n bá tún ń ṣe bẹ́ẹ̀. Ẹ ṣeun. Agbalagba (ọ̀rọ̀) 13:37, 22 Oṣù Kínní 2021 (UTC)
Start a discussion about Àbò
Talk pages are where people discuss how to make content on Wikipedia the best that it can be. You can use this page to start a discussion with others about how to improve Àbò.