Ọ̀rọ̀:ÌFÁÀRÀ LÓRÍ ÀÀLỌ́

Àkíyèsí pàtàkì

àtúnṣe

Mo kí oníṣẹ́ Basmore, pé ẹ kú iṣẹ́ takun-takun tí ẹ ń gbé ṣe lórí àkọsílẹ̀ àwọn àlọ́ àpagbè tí ẹ ń kọ sílẹ̀ sí orí Wikipedia èdè Yorùbá, inú wa dùn fún àwọn àfikún náà. Àmó, báwo ni kò bá ṣe dára tó kí àwọn àyọkà náà ó ní àwọn ìtọ́ka sí tó dára, kódà bí kò ju ẹyọ mẹ́ta mẹ́ta lọ. 1. Ẹ lè lo àwọn ìwé tí ẹ ṣàmúlò wọn láti fi ṣe ìtọ́ka sí fún àwọn ayọkà yín kí wọ́n ba lè bójú mu.

2. Ẹ ma rántí láti ma lo àmì sórí àwọn àyọkà yín ọ̀hún, bí ẹ bá nílò ìrànwọ́ kan tàbí òmíràn láti ọ̀dọ̀ mi, ẹ lè kàn sí mi.


Ẹ ṣeun Agbalagba (ọ̀rọ̀) 13:42, 12 Oṣù Kejìlá 2022 (UTC)

Return to "ÌFÁÀRÀ LÓRÍ ÀÀLỌ́" page.