Ọ̀rọ̀:Aṣọ Òfì
Ẹǹlẹ́ Àgbàlagbà, molérò pé lópin ìgbà tí àwòrán òún tí àdàkọ náà n se ìjúwe rè ò ti sí níbẹ̀, kò fẹ́ẹ̀ ṣànfàní pẹ̀lú bíbẹ rẹ̀ níbẹ̀, ìdí èyí ló mú mi yọ́kúrò. Osenibabalola0 (ọ̀rọ̀) 21:07, 6 Oṣù Keje 2021 (UTC)
- Ẹ kú iṣẹ́ Oníṣe:Osenibabalola0, ṣé ẹ lè gbìyànjú láti fi àwọn ìtọ́ka sí àyọkà Chermoula tí ẹ kọ, nítorí kí á lè mọ̀ òdodo pàtó nípa àyọkà náà, bí bẹ́ẹ̀ kọ́, a paárẹ́ kúrò lójú ewé wa. Ẹ ṣeun.Agbalagba (ọ̀rọ̀) 07:16, 9 Oṣù Keje 2021 (UTC)
Start a discussion about Aṣọ Òfì
Talk pages are where people discuss how to make content on Wikipedia the best that it can be. You can use this page to start a discussion with others about how to improve Aṣọ Òfì.