Arukaino Umukoro

Oníwé-Ìròyín
(Àtúnjúwe láti Ọ̀rọ̀:Arukaino umukoro)
Ìwé-alàyé[ìdá]

Arukaino Umukoro je akọ̀wé lá tí orílẹ̀de Nàìjíríà tí a mọ fún bíborí CNN/MultiChoice Africa Journalist Award ni ọdún 2015.[1][2]

Arukaino Thomas Umukoro
Ọjọ́ìbíArukaino Umukoro
Ẹ̀kọ́Delta State University
Pan-Atlantic University
Iṣẹ́Journalist
Public Servant

Ìwé kíkà Umukoro kàwé gboyẹ̀ nínú Industrial Chemistry ni Fáṣítì ti ìlú Delta, ó túbọ̀ lọ sí the Nigerian Institute of Journalism tí ó sì sàsẹ́yege ìwé kíkà naa. Ní ọdún 2016, Umukoro parí ẹ̀kọ́ Master's rẹ̀ lórí iṣẹ́ Media and Communication ní Fásiti tí amọ̀ sí Pan-African University.[3]

Iṣe ṣíṣe

àtúnṣe

Lèyìn ti Umukoro kẹ́kọ̀ọ́ gboyẹ̀ lórí ẹ̀kọ́ ìwé kíkà, ó bt Iṣẹ́ kíkà ìròyìn ní ilé iṣé ìwé ìròyìn National Standard News ni ọdún 2007. Iṣe Umukoro ni ìwé kíko bẹ̀rẹ̀ nígbà tí ó ń ṣíṣe sísọ ìròyìn lọ́dọ̀ the National Standard news magazine ni ọdún 2007. Ó gbà àmì ẹ̀yẹ fún Writer of the Year’ award ni ọdún 2007 ni ilé-iṣẹ́ ìròyìn The National Standard. Ó tún bọ̀ dára pọ̀ mọ́ wọn ní ilé iṣé The stables of Tell Magazine láti báwo ṣiṣẹ́. Lèyìn èyi ó ṣíṣe ní ilẹ̀ iṣẹ ìròyìn The Punch Newspaper níbi tí ó ti dì Oga . Umukoro já èwè Olúborí nínú ìdílje The Nigeria Media Merit Award fún ìgbà Kínní ni ọdún 2013, eyi tí ó tún gbà àmi ẹyẹ lekan sì ni ọdún 2017.[4]

Ni ọdún 2015, wọ́n fún ní àmì ẹyẹ kan ní CNN/MultiChoice Africa Journalist nípa tí ìsòrí eré ìdárayá.[5]

Ó tunbọ̀ jáwé olúborí nínú ìdíje ti S.O. Idowu Prize fún sísọ ìròyìn eré ìdárayá tí ó jé wípé ó gba ipò Kejì ní ọdún 2017.[6] Ní 2017, Ó jẹ ipò gẹ́gẹ́ bí agbẹnusọ ati iṣ ìbánisọ́rọ́ fún Ààrẹ ìgbà Kejì orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Yẹmí Òsínbàjò. 7][8]

Àwọn Ìtọ́kasi

àtúnṣe
 Empty citation (help) 
  1. "CNN MULTICHOICE AFRICAN JOURNALIST 2015 FINALISTS ANNOUNCED". cnnpressroom.blogs.cnn.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2018-03-27. Retrieved 2018-03-27. 
  2. "Nigerians steal show at African Journalists of the Year Awards". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2015-10-09. Retrieved 2022-03-25. 
  3. "Arukaino Umukoro". LinkedIn. 
  4. "PUNCH wins Newspaper of the Year, Aboderin honoured at NMMA" (in en-US). Punch Newspapers. http://punchng.com/punch-wins-newspaper-of-the-year-aboderin-honoured-at-nmma/. 
  5. International, CNN (2018-01-04). "2015". africa.cnnjournalistaward.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2018-06-21. Retrieved 2018-03-27.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)