Ọ̀rọ̀:Duro Ladipo
- Mi ò rò wípé ó yẹ kí oníṣé T Cells ó fi léde láti yọ ojú ewé Dúró Ládípọ̀ kúrò nínú ìwé ìmọ̀ ẹ̀kọ́ ọ̀fẹ́ nítorí wípé kò gbé ẹnìkẹ́ni lárugẹ tàbí polówó ọjà tàbí oníbàrà kan kan, ojú ewé yìí wà ní ìbámu pẹ̀lú ẹ̀dà en.wikipedia. Mi ò bá rọ̀ yín kí ẹ tún ìpinnu yín yẹ̀wò lẹ́ẹ̀kan si. Ẹ ṣé Agbalagba (ọ̀rọ̀) 13:10, 22 Oṣù Kàrún 2018 (UTC)
Start a discussion about Duro Ladipo
Talk pages are where people discuss how to make content on Wikipedia the best that it can be. You can use this page to start a discussion with others about how to improve Duro Ladipo.