Àkíyèsí pàtàkì

àtúnṣe

@Ogbon ologbon92, mo kíi yín fún iṣẹ́ takuntakun tí ẹ ń gbé ṣe lórí Wikipedia Yorùbá. Mo ṣ fẹ́ pè yín sí àkíyèsí pàtàkì kan nípa àyọkà Eye okin tí ẹ ṣẹ̀ṣẹ̀ da sílẹ̀. Mo ma gbà yín ní ìyànjú wípé kí ẹ ṣe àkọkún sí àyọkà náà kí ẹ sì fi àwọn orísun ìtọ́kasí tí ó bá yẹ sí àwọn kókó ọ̀rọ̀ tí ẹ bá mẹ́nubà nínú àyọkà ọ̀hún. Ẹ ṣeun púpọ̀.Agbalagba (ọ̀rọ̀) 22:33, 27 Oṣù Kínní 2024 (UTC)

Return to "Eye okin" page.