Ọ̀rọ̀:Lara ati awọn Lu

Ìṣòro ṣíṣe ògbufọ̀ àwọn àkọlé àyọkà

àtúnṣe

ẹ ǹ lẹ́ o. Mo ṣàkíyèsí pé ẹ tú àkọlé fíìmù yìí sí èdè Yorùbá,mi ò sì rò pé ó yẹ bẹ́ẹ̀. Níwọ̀n ìgbà tó jẹ́ pé àkọlé fíìmù ni, ẹ jẹ́ a fi í lẹ̀ bó ṣe wà. A ò nílò láti tú u sí èdè Yorùbá. Ẹ ṣeun Ọmọladéabídèmí99 (ọ̀rọ̀) 06:14, 12 Oṣù Kejì 2024 (UTC)

Return to "Lara ati awọn Lu" page.