Ọ̀wọ́n Gbọ̀ngàn Tinúbu

Ọ̀wọ́n Gbọ̀ngàn Tinubu (tí a n pe ni Ọ̀wọ́n Gbọ̀ngàn Òmìnira tẹ́lẹ̀ rí), jẹ ọwọn manigbagbe ti o wa ni opopona gbooro (Broad Street), ni Erekusu Eko (Lagos Island), ni Ipinle Eko, ni orilẹ-ede Naijiria. [1] Ni igba kan ri, Ita Tinubu ni a npe ni irati Iyaafin Efunroye Tinubu [2] ti o je oniṣowo ẹrú ati gbajugbaja oniṣowo, ki o to di pe a yi orukọ rẹ pada si Ọ̀wọ́n Gbọ̀gàn Ominira lati owo awon oludari eto iṣejọba ara ẹni akoko ni Orilẹ-ede Naijiria, leyin eyi ni a tun wa yi oruko re pada si Ọ̀wọ́n Gbọ̀ngàn Tinubu. [3]

Madam Tinubu ṣaaju ọdun 1887

Àgbékalẹ̀

àtúnṣe

Gbọ̀ngàn yii je onigun-mẹrin ti a fi irin se odi yii kaakiri, o si ni orisun omi meji ti o nfan omi si awon ododo ati awon igi ilẹ̀ olóoru ti o wa ninu rẹ̀. Ère Iyaafin Tinubu ti o ga to iwon eniyan wa ninu Gbọ̀ngàn yii o si duro lori orori kan. [3]

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe