Ọọ̀ni Adekola
Ooni Adekola ni Ọọ̀ni ẹlẹ́ẹ̀kẹtàdínláàádọ́ta tó jẹ olórí ìbílẹ̀ ti Ilé-Ifẹ̀, tí ń ṣe orírun àwọn ọmọ Yorùbá. Lẹ́yìn tí Ọọ̀ni Adelekan Olubuse I wàjà ni ó gorí oyè, Ọọ̀ni Ademiluyi Ajagun ló sì jẹ oyè yìí lẹ́yìn tí òun náà wàjà.[1]
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Dayo, Ologundudu (2008). The cradle of Yoruba culture. Nigeria: Centre for spoken words. p. 206. ISBN 978-0615220635. https://books.google.com/books?id=Vn8uAQAAIAAJ&q=Ooni+Ojigidiri&dq=Ooni+Ojigidiri. Retrieved July 30, 2015.