Ọọ̀ni Ekun
Ooni Ekun ni Ọọ̀ni ẹlẹ́ẹ̀kẹtàlá ti Ilé-Ifẹ̀ tó jẹ́ olórí ìbílẹ̀ ti Ilé-Ifẹ̀, tí ń ṣe orírun àwọn ọmọ Yorùbá. Lẹ́yìn tí Ọọ̀ni Odidimode Rogbeesin wàjà ni EKun jẹ oyè yìí, tí Ọọ̀ni Ajimuda sì jẹ oyè yìí lẹ́yìn rẹ̀.[1]
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Dayo, Ologundudu (2008). The cradle of Yoruba culture. Nigeria: Centre for spoken words. p. 206. ISBN 978-0615220635. https://books.google.com/books?id=Vn8uAQAAIAAJ&q=Ooni+Ojigidiri&dq=Ooni+Ojigidiri. Retrieved July 30, 2015.