Ọbańta (tí orúkọ rẹ̀ gangan ń jẹ́Ogborogan) jẹ́ ọba aládé kẹta tí Ìjẹ̀bú, tí ó di Ìpínlẹ̀ Ogun lórílẹ̀ èdè Nigeria báyìí láti sẹ́ńtúrì kẹrìnlá .[1][2][3]

Obanta
Awujale of Ijebu Kingdom

Reign 14th century
Born Ile Ife
Died Nigeria
Religion Yoruba

Ọbańta kó àwọn ènìyàn láti Ilé-Ifè wá sí Ìjẹ̀bú Òde níbi tí ó ti jọba lẹ́yìn tí bàbá ìyá rẹ̀, Ọba Olú Ìwà, Awùjalẹ̀ àkọ́kọ́ Ìjẹ̀bú Òde kú. Ní kété tí ó dé Ìjẹ̀bú Òde, àwọn ará ìbè gbáà tọwọ́tẹsẹ̀, tí wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí ní kí í pé Ọba ìlú wà ní ìta. Èyí ni bí ọba Ogborogan ṣe ń jé Ọbańta.[4]

Àwọn ìrandíran Ọ̀bańta sì bẹ̀rẹ̀ sí ní joyè Awùjalẹ̀ tí Ìjẹ̀bú Òde, bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àwọn olóyè rẹ̀ máa ń dín agbára rẹ̀ kù. [5]

Titi di òní, ère rẹ̀ tí wọ́n fi bọlá fún un ṣì wà ní ìlú Ìjẹ̀bú Òde lẹ́bàá Itale.

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Nigeria Magazine. Federal Ministry of Culture and Social Welfare. Government of Nigeria, Indiana University. 1965. p. 177. https://books.google.com/books?id=mRYOAQAAMAAJ. 
  2. Bernard I. Belasco (1980). The entrepreneur as culture hero: preadaptations in Nigerian economic development. Praeger(University of Michigan). p. 72. https://books.google.com/books?id=2PwNAQAAMAAJ. 
  3. Ifẹ̀: Annals of the Institute of Cultural Studies, University of Ife, Nigeria. Obafemi Awolowo University. Institute of Cultural Studies. 1986. https://books.google.com/books?id=QDE8AQAAIAAJ. 
  4. Robert Smith (1969). Kingdoms of the Yoruba. Methuen & Co. pp. 77–78. https://books.google.com/books?id=ric6OhxbCS0C&pg=PA77. 
  5. Robert Smith (1969). Kingdoms of the Yoruba. Methuen & Co. p. 79. https://books.google.com/books?id=ric6OhxbCS0C&pg=PA78.