Ọgbẹlẹ ni Òrilẹ ede Naìjìrìá
Ọgbẹlẹ fun igba pipẹ Ni órilẹ ede Naijiria ti jasi iparẹ̀ awọn igi, koriko ati ilẹ ti a fin sin maalu tabi gbin kan ókó[1][2][3].
Lati ri ilẹ fun oko ati nkan isin, awọn oloko ati dàran dàran ni wọn maa ngbiyanju lati lọsi agbegbe tuntun eyi lo maa ṣaba jasi jakidijagan[4]. Awọn oloko ati dàran dàran maa n kopa ninu ija jakidijagan lati ọdun meji sẹyin eyi lo ti jasi iku awọn eniyan ẹgbẹrun mẹji ni ọdun 2018[5][6]. Ọpọ ninu awọn ara abule ipinlẹ Plateau ni wọn ko fẹ kuro ni agbegbe naa toripe wọn ri gẹ́gẹ́ bi ile[7]. Ti adugbo kan ba jo, blocku tuntun miran ni wọn maa fi ntu awọn ile to ti bajẹ naa ṣe[8].
Ọgbẹlẹ jẹ iṣẹlẹ to maa n ṣẹlẹ ni órilẹ́ ede Naijiria ti o si maa koba gbogbo orilẹ. Ni ariwa ilẹ Naijria, akaimoye iṣẹlẹ ọgbẹlẹ lo ti waye to si ja si Ìyàn ni ọdun 1914, 1924, 1935, 1943, 1951–1954, 1972–1973, Mortimore 1989 and 1991–1995[9].
Iwadi aipẹ ti awọn SBMIntel, Awọn ilè iṣè oluṣewadi ti ilẹ Africa sọpe 79% awọn agbẹn ni ọgbẹlẹ ati Ikun Omi ti koba ni ọdun 2020. Lara wọn, 26.3% ṣè ajalu adikun ninu ere ókó wọn latara oju ọjọ tiko fararọ. Iwadi ti a pe akọle rẹ ni "Awọn ọmọ órilẹ ede Naijiria fẹ jẹun" sọ nipa awọn ipenija ti awọn agbẹ naijiria ati awọn to ko óunjẹ ṣe irinajo dojukọ eyi to si le kopa abojuto ounjẹ órilẹ ede[10].
Ìpà Ọgbẹlẹ
àtúnṣeỌgbẹlẹ ti jasi alekun ba ayipada ninu oju ọjọ lagbaye[11]. Iwadi Ọgbẹlẹ to ṣẹlẹ ni ọdun 1973 sọpe ọpọlọpọ eniyan ni wọn padanu ẹmi wọn ninu iṣẹlẹ to si mu adinku ba iṣẹ agbẹ. Iwadi yi lofihan pe eniyan 10.3 millionu ni apa ariwa naijiria lo koju ìyan ti aimoye maalu si ku[1]. Ni ọdun 1978, iṣẹlẹ miran waye to jasi adanu óun ọgbin bi agbado ati sorghum latari ọgbẹlẹ.
Ayipada nla ni ipa ti ọgbẹlẹ ko ariwa ilẹ Naijiria lati ọdun sẹyin to si koba oun ọgbin ati ere ókò ni agbegbe naa[12][13].
Ọgbẹlẹ jẹ adinku tabi airi rara omi lori ilẹ latari airi òjó fun igba pipẹ ni agbègbè naa. Èyi lo jasi ki oun ọgbin ko kuna latari airi omi. Nigba ọgbẹlẹ, Àgbara Ẹrọ amunawa maa ndiku to si maa nko ipalara ba awọn iṣẹ to gbẹkẹle[14].
Awọn itọkasi
àtúnṣe- ↑ 1.0 1.1 Sunday, Orji (2021-01-11). "Nigeria cattle crisis: how drought and urbanisation led to deadly land grabs". the Guardian. Retrieved 2023-09-02.
- ↑ Shiru, Mohammed Sanusi; Shahid, Shamsuddin; Dewan, Ashraf; Chung, Eun-Sung; Alias, Noraliani; Ahmed, Kamal; Hassan, Quazi K. (2020-06-22). "Projection of meteorological droughts in Nigeria during growing seasons under climate change scenarios". Scientific Reports (Springer Science and Business Media LLC) 10 (1). doi:10.1038/s41598-020-67146-8. ISSN 2045-2322.
- ↑ "Briefing: Nigerian farmers can’t fight desertification alone". The New Humanitarian. 2017-11-14. Retrieved 2023-09-02.
- ↑ "Herders against Farmers: Nigeria’s Expanding Deadly Conflict". Crisis Group. 2017-09-19. Retrieved 2023-09-02.
- ↑ "Stopping Nigeria’s Spiralling Farmer-Herder Violence". Crisis Group. 2018-07-26. Retrieved 2023-09-02.
- ↑ Salkida, Ahmad (2020-06-13). "Fulani: Villain And Victim Of Militia Attacks?". HumAngle. Retrieved 2023-09-02.
- ↑ "They Do Not Own This Place: Government Discrimination Against "Non-Indigenes" in Nigeria: Historical Background and Context". Human Rights Watch. 2005-11-18. Retrieved 2023-09-02.
- ↑ "Drought in Nigeria". Greenpeace. Retrieved 2023-09-02.
- ↑ Eze, Jude Nwafor (2018-10-22). "Drought occurrences and its implications on the households in Yobe state, Nigeria". Geoenvironmental Disasters (Springer Science and Business Media LLC) 5 (1). doi:10.1186/s40677-018-0111-7. ISSN 2197-8670.
- ↑ "Nearly 80% of Nigerian farmers affected by floods, drought in 2020". Premium Times Nigeria. Retrieved 2023-09-02.
- ↑ Hassan, A.G.; Fullen, M.A.; Oloke, D. (2019). "Problems of drought and its management in Yobe State, Nigeria". Weather and Climate Extremes (Elsevier BV) 23: 100192. doi:10.1016/j.wace.2019.100192. ISSN 2212-0947.
- ↑ Doya, Khalid Idris (2023-06-11). "ACReSAL Project To Reclaim Degraded 1m Hectares Of Land In Northern Nigeria". Leadership News. Retrieved 2023-09-02.
- ↑ Royal, David O (2021-10-22). "Northern farmers face poor harvest as drought blights early farming". Vanguard News. Archived from the original on 2023-09-02. Retrieved 2023-09-02.
- ↑ "Climate crisis in Nigeria: No more a distant matter (2) – The Sun Nigeria". The Sun Nigeria. 2023-08-16. Retrieved 2023-09-02.