Ọjọ́ Ẹtì

Àdàkọ:Other uses Àdàkọ:Use mdy dates

Ọjọ́ Ẹtì jẹ́ ojú kan láàrin ọsẹ tí ó wà láàrin ọjọ́bọ̀ àti Ọjó àbámẹ́ta. Ní àwọn orílẹ̀-èdè èdè tí wọn ń ló Ọjọ ìṣẹgun gẹgẹ bí àkọkọ́ ọjọ́ nínú ọ̀sẹ̀, ọjọ ẹtì jẹ́ ọjọ karún nínú ọ̀sẹ̀. Amọ̀ ní àwọn orílẹ̀-èdè mìíràn, ọjọ ẹtì ní ojú kẹfà nínú ọ̀sẹ̀ fún àwọn tí wọn ń ló ọjọ Àìkú gẹ́gẹ́ bí àkọkọ́ ọjọ nínú ọ̀sẹ̀.