Ọkàn je agbarajo inu ara àwon elemi to un fun ẹ̀jẹ̀ ni ite lati ba le yi ka kiri inu isan agbeje.