Ọlájùmọ̀kẹ́ Òrìṣàgúnà
Olajumoke Orisaguna | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 1989 (29 years old) Ire, State of Osun, Nigeria |
Ibùgbé | Lagos, Nigeria |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Orúkọ míràn | Bread seller (omo oni bread), Nigeria's Cinderella |
Iṣẹ́ | Model |
Olólùfẹ́ | Sunday Orisaguna |
Àwọn ọmọ | 2 |
Ọlájùmọ̀kẹ́ Òrìṣàgúnà tí wọ́n bí ọdún 1989 jẹ́ awẹ́lẹ́wà àti aláwòkọ́ṣe ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí ó di gbajúmọ̀ ìlúmọ̀ọ́kà nígbà tí ó ń kiri búrẹ̀dí ni ìlú Èkó tí orí sìn gbé e ko olóore. Ó jẹ́ ọmọ bíbí ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun tí ó kiri búrẹ́dì tà ní Èkó.[1][2]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ From bread seller to top model: How a photobomb created a star, Stephani Bugari, 12 February 2016, CNN, Retrieved 25 April 2016
- ↑ "Olajumoke: 'Tinie Tempah photobomb transformed my life'". BBC News. 21 August 2017. https://www.bbc.com/news/av/world-africa-40981052/olajumoke-tinie-tempah-photobomb-transformed-my-life. Retrieved 14 June 2019.