Ọpọlọ ènìyàn
Ọpọlọ ènìyàn ni ẹ̀yà ara tí ó wà nínú orí ọmọnìyàn tí ó sì jẹ́ ọ̀gangan irinṣẹ́ tí ó ń ṣàkóso gbogbo iṣan inú ara ènìyàn pátá pátá, pẹ̀lú ìrànlọ́wọ́ egungun ẹ̀yìn.
Ọpọlọ ènìyàn | |
---|---|
Human brain and skull | |
Details | |
Precursor | Neural tube |
System | Central nervous system Neuroimmune system |
Artery | Internal carotid arteries, vertebral arteries |
Vein | Internal jugular vein, internal cerebral veins; external veins: (superior, middle, and inferior cerebral veins), basal vein, and cerebellar veins |
Latin | Cerebrum[1] |
Greek | ἐγκέφαλος (enképhalos)[2] |
Anatomical terminology |
Ọ̀nà tí ọpọlọ pín sí
àtúnṣeỌpọlọ pín sí orísi ọ̀nà mẹ́ta:
- cerebrum,
- brainstem, àti
- cerebellum.
Ọpọlọ ni ohun tí ó ń ṣàkóso ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìṣesí àgọ́ ara, nípa ṣíse ìgbésẹ̀, sísopọ̀ àti ìṣàkóso gbogbo ohun tí ó bá ń ṣe gba inú àgọ́ ara kọjá lásìkò kan. Ó ma ń ṣe ìpinu lórí ohun-kóhun tó ṣẹ̀lẹ̀ sí ènìyàn, tí yóò sì jẹ́ kí gbogbo ara ó mọ ohun tí ó ń ṣẹlẹ̀ lọ́wó lọ́wọ́. Inú egungun agbárí ẹ̀nìyan ni ọpọlọ wà ní orí ènìyàn.
Sẹ̀ríbúrọ́ọ́mù ni ó jẹ́ ìpín ọpọlọ tí ó tóbi jùlọ nínú àwọn ìpín ọpọlọ ọmọnìyàn. Sẹ̀ríbúrọ́ọ̀mù yí náà tún wá pín sí oríṣi méjì, àwọn ni:
- cerebral cortex, èyí ni ó dà bí awọ fẹ́lfẹ́ tí ó wà lókè tí ó sì bo white matter. Cotex yí ni ó tún pín sí neocortex àti allocortex tí ó sì kéré jùlọ
Èyíkeyì nínú àwọn ìpín ọpọlọ yí ni wọ́n so pọ̀ pẹ̀lú commissural nerve tracts, tí ó jẹ́ corpus callosum.
Ẹ̀ka ẹ̀kọ́ nípa ọpọlọ
àtúnṣeẸ̀ka ẹ̀kọ́ tí ó níṣe pẹ̀lú ìkẹ́kọ̀ọ́ nípa ọpọlọ ni wọ́n ń pè ní neuroanatomy, nígbà tí ìkẹ́kọ̀ọ́ nípa bí ọpọlọ ṣe ń ṣiṣẹ́ ni wọ́n ń pè ní neuroscience. Oríṣiríṣi ìlànà ni wọ́n ń gbà kẹ́kọ̀ọ́ àtibṣe ìwádí nípa ọpọlọ, lára rẹ̀ ni Specimens láti ara àwọn ẹranko ni examined microscopically.[3]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Àdàkọ:Cite dictionary
- ↑ Àdàkọ:Cite dictionary
- ↑ Fan, Xue; Markram, Henry (2019-05-07). "A Brief History of Simulation Neuroscience". Frontiers in Neuroinformatics 13: 32. doi:10.3389/fninf.2019.00032. ISSN 1662-5196. PMC 6513977. PMID 31133838. //www.pubmedcentral.nih.gov/articlerender.fcgi?tool=pmcentrez&artid=6513977.