Ọ̀rọ̀-ìṣe

(Àtúnjúwe láti Ọrọ ìṣe)

Ọ̀rọ̀-ìṣe ni òpómúléró, tàbí kókó ọ̀rọ̀ inú gbólóhùn èdè Yorùbá . Òhun ni ó máa sọ ohun ti olùwà ṣe nínú gbólóhùn.

Àpẹẹrẹ: Wálé jẹ iṣu (jẹ ni ọ̀rọ̀ ìṣe nínú gbólóhùn yìí) https://en.m.wikipedia.org/wiki/Verb.