Ọyẹ́
Ọyẹ́ jẹ́ àsìkò kan lápá ìwọ̀-oòrùn Áfíríkà tí ó má a ń wáyé láàárín ìparí oṣù kọkànlá sí àárín oṣù kẹta ọdún. Ó jẹ́ àsìkò ẹrùn tàbí ọ̀gbẹlẹ̀ tí ó máa ń fa eruku.[1] Orúkọ náà farajọ ọ̀rọ̀ náà ọyẹ́, ní èdè Twi.[2] Ó má a ń jẹ́ àsìkò òtútù, ní àwọn àgbègbè mìíràn ẹ̀wẹ̀, ó máa ń jẹ́ àsìkò oru, èyí máa ń dá lórí àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ ojú ọjọ́ ní irú àgbègbè bẹ́ẹ̀.[3]
Afẹ́fẹ́ Ọyẹ́ máa ń fẹ́ lásìkò ẹ̀rùn tàbí ọ̀gbẹlẹ̀, ní àsìkò tí ọ̀òrùn kì í fi bẹ́ẹ̀ ràn dáradára.
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Harmattan". Encyclopædia Britannica. Retrieved 22 July 2015.
- ↑ Àdàkọ:Cite dictionary
- ↑ Geographical Review (1919): "Knox writes of this wind : The Harmattan is experienced as a wind which blows, especially in the months of December, January, and February, from the NE. and is a hot wind in some localities and a cold wind in others, according to circumstances."