143 Adria
143 Adria jẹ́ ìgbàjá ìsọ̀gbé oòrùn kékeré tí ó sì fẹ̀ díẹ̀ tí Onímọ̀ ìwòràwọ̀ J. Palisa ọmọ orílẹ̀ èdè Australia ṣàwárí rẹ̀ ní ní Ọjọ́ kẹtàlélógún Oṣù kejì Ọdún 1875 ní Pula, ó sì sọọ́ lórúkọ Adriatic Sea níbi tí ó ti ṣàwárí rẹ̀.
Ìkọ́kọ́wárí[1] and designation
| |
---|---|
Kíkọ́kọ́wárí látọwọ́ | Johann Palisa |
Ọjọ́ ìkọ́kọ́wárí | 23 February 1875 |
Ìfúnlọ́rúkọ
| |
Sísọlọ́rúkọ fún | Adriatic Sea |
Minor planet category |
Main belt |
Àsìkò 31 July 2016 (JD 2457600.5) | |
Aphelion | 2.9654 AU (443.62 Gm) |
Perihelion | 2.55537 AU (382.278 Gm) |
Semi-major axis | 2.76036 AU (412.944 Gm) |
Eccentricity | 0.074263 |
Àsìkò ìgbàyípo | 4.59 yr (1675.1 d) |
Average orbital speed | 17.90 km/s |
Mean anomaly | 225.257° |
Inclination | 11.449° |
Longitude of ascending node | 333.069° |
Argument of perihelion | 253.346° |
Ẹ̀gbẹ̀ẹ̀gbẹ́ | 89.93±1.9 km |
Àkójọ | 7.6 × 1017 kg |
Iyeìdáméjì ìṣùpọ̀ | 2.0 g/cm³ |
Equatorial surface gravity | 0.0251 m/s² |
Equatorial escape velocity | 0.0475 km/s |
Rotation period | 22.005 h (0.9169 d)[2][3] |
Geometric albedo | 0.0491±0.002 |
Ìgbónásí | ~167 K |
Spectral type | C |
Absolute magnitude (H) | 9.12 |
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ [1]
- ↑ 2.0 2.1 Yeomans, Donald K., "143 Adria", JPL Small-Body Database Browser, NASA Jet Propulsion Laboratory, retrieved 12 May 2016.
- ↑ Pilcher, Frederick (September 2008), "Period Determinations for 26 Proserpina, 34 Circe 74 Galatea, 143 Adria, 272 Antonia, 419 Aurelia, and 557 Violetta", The Minor Planet Bulletin, 35 (3), pp. 135–138, Bibcode:2008MPBu...35..135P.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |